1 Sámúẹ́lì 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+
18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+