ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 16:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Níkẹyìn, Sámúẹ́lì béèrè lọ́wọ́ Jésè pé: “Ṣé gbogbo àwọn ọmọkùnrin rẹ nìyí?” Ó fèsì pé: “Èyí tó kéré jù+ ṣì wà níta; ó kó àwọn àgùntàn lọ jẹ koríko.”+ Ni Sámúẹ́lì bá sọ fún Jésè pé: “Ní kí wọ́n lọ pè é wá, torí ó dìgbà tó bá dé ká tó jókòó láti jẹun.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́