Àwọn Onídàájọ́ 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà wá bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, torí náà, ó fi wọ́n lé àwọn tó ń kóni lẹ́rù lọ́wọ́.+ Ó fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká,+ apá wọn ò sì ká àwọn ọ̀tá wọn mọ́.+ Sáàmù 89:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Mo ti rí Dáfídì ìránṣẹ́ mi;+Mo ti fi òróró mímọ́ mi yàn án.+ Sáàmù 89:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọ̀tá kankan kò ní gba ìṣákọ́lẹ̀* lọ́wọ́ rẹ̀,Aláìṣòdodo kankan kò sì ní fìyà jẹ ẹ́.+
14 Jèhófà wá bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, torí náà, ó fi wọ́n lé àwọn tó ń kóni lẹ́rù lọ́wọ́.+ Ó fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká,+ apá wọn ò sì ká àwọn ọ̀tá wọn mọ́.+