-
Jeremáyà 33:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Bí a kò ti lè ka àwọn ọmọ ogun ọ̀run, tí a kò sì lè wọn iyanrìn òkun, bẹ́ẹ̀ ni màá sọ àtọmọdọ́mọ* Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n ń ṣe ìránṣẹ́ fún mi di púpọ̀.’”
-