2 Sámúẹ́lì 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ 1 Kíróníkà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, Dáfídì sọ pé: “Ẹni tó bá kọ́kọ́ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì ló máa di balógun* àti ìjòyè.” Jóábù+ ọmọ Seruáyà ló kọ́kọ́ lọ, ó sì di balógun.
23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+
6 Torí náà, Dáfídì sọ pé: “Ẹni tó bá kọ́kọ́ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì ló máa di balógun* àti ìjòyè.” Jóábù+ ọmọ Seruáyà ló kọ́kọ́ lọ, ó sì di balógun.