Diutarónómì 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára.+ Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì gbọ̀n rìrì níwájú wọn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń bá yín lọ. Kò ní pa yín tì, kò sì ní fi yín sílẹ̀.”+
6 Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára.+ Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì gbọ̀n rìrì níwájú wọn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń bá yín lọ. Kò ní pa yín tì, kò sì ní fi yín sílẹ̀.”+