2 Sámúẹ́lì 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ní kí àwọn òjíṣẹ́ lọ mú un wá.+ Torí náà, ó wọlé wá bá a, ó sì bá a sùn.+ (Èyí ṣẹlẹ̀ nígbà tí obìnrin náà ń wẹ ara rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ohun àìmọ́*+ rẹ̀.) Lẹ́yìn náà, ó pa dà sílé rẹ̀.
4 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ní kí àwọn òjíṣẹ́ lọ mú un wá.+ Torí náà, ó wọlé wá bá a, ó sì bá a sùn.+ (Èyí ṣẹlẹ̀ nígbà tí obìnrin náà ń wẹ ara rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ohun àìmọ́*+ rẹ̀.) Lẹ́yìn náà, ó pa dà sílé rẹ̀.