-
2 Sámúẹ́lì 7:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àfi bíi pé ìyẹn ò tó, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, o tún sọ nípa ilé ìránṣẹ́ rẹ títí lọ dé ọjọ́ iwájú tó jìnnà; èyí sì jẹ́ ìtọ́ni* fún gbogbo aráyé, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.
-