-
2 Sámúẹ́lì 10:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Dáfídì bá sọ pé: “Màá fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí Hánúnì ọmọ Náháṣì, bí bàbá rẹ̀ ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi.” Torí náà, Dáfídì rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ láti lọ tù ú nínú nítorí bàbá rẹ̀ tó kú. Àmọ́ nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì dé ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì,
-