-
2 Sámúẹ́lì 11:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ni Dáfídì bá sọ fún òjíṣẹ́ náà pé: “Sọ fún Jóábù pé: ‘Má ṣe jẹ́ kí ọ̀ràn yìí dà ọ́ láàmú, kò sẹ́ni tí idà ò lè pa lójú ogun. Túbọ̀ múra sí ìjà tí ò ń bá ìlú náà jà, kí o sì ṣẹ́gun rẹ̀.’+ Kí o bá mi fún Jóábù ní ìṣírí.”
-