Òwe 18:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọmọ ìyá tí a ṣẹ̀, ó le ju ìlú olódi lọ,+Àwọn ìjà kan sì wà tó dà bí ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè ilé gogoro tó láàbò.+
19 Ọmọ ìyá tí a ṣẹ̀, ó le ju ìlú olódi lọ,+Àwọn ìjà kan sì wà tó dà bí ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè ilé gogoro tó láàbò.+