ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Níkẹyìn, Ádóníjà fi àgùntàn àti màlúù pẹ̀lú ẹran àbọ́sanra rúbọ+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkúta Sóhélétì, èyí tó wà nítòsí Ẹn-rógélì, ó pe gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àwọn ọmọ ọba àti gbogbo ọkùnrin Júdà tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ ọba.

  • 1 Àwọn Ọba 1:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ó fi akọ màlúù àti ẹran àbọ́sanra pẹ̀lú àgùntàn tó pọ̀ gan-an rúbọ, ó pe gbogbo ọmọ ọba àti àlùfáà Ábíátárì pẹ̀lú Jóábù olórí ọmọ ogun;+ àmọ́ kò pe Sólómọ́nì ìránṣẹ́ rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́