-
2 Sámúẹ́lì 14:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àmọ́ ọba sọ pé: “Ilé rẹ̀ ni kí ó pa dà sí, kò gbọ́dọ̀ fojú kàn mí.” Torí náà, Ábúsálómù pa dà sí ilé rẹ̀, kò sì fojú kan ọba.
-