-
Jẹ́nẹ́sísì 45:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ó wá fi ẹnu ko gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ lẹ́nu, ó sì ń sunkún bó ṣe ń dì mọ́ wọn, lẹ́yìn náà, àwọn arákùnrin rẹ̀ bá a sọ̀rọ̀.
-