Òwe 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹnu ni apẹ̀yìndà* fi ń fa ìparun bá ọmọnìkejì rẹ̀,Àmọ́ ìmọ̀ ló ń gba àwọn olódodo sílẹ̀.+