ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ sínú ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ.” Dáfídì bá béèrè pé: “Ibo ni kí n lọ?” Ó fèsì pé: “Lọ sí Hébúrónì.”+

  • 2 Sámúẹ́lì 5:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà tó yá, gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì,+ wọ́n sì sọ pé: “Wò ó! Ẹ̀jẹ̀* kan náà ni wá.+

  • 2 Sámúẹ́lì 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ọdún méje àti oṣù mẹ́fà ló fi jọba lórí Júdà ní Hébúrónì, ó sì fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) ṣàkóso lórí gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà ní Jerúsálẹ́mù.+

  • 1 Kíróníkà 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àwọn mẹ́fà yìí ni wọ́n bí fún un ní Hébúrónì; ọdún méje àti oṣù mẹ́fà ló fi jọba níbẹ̀, ó sì fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) jọba ní Jerúsálẹ́mù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́