Ẹ́kísódù 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “O ò gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ òdì sí* Ọlọ́run+ tàbí kí o sọ̀rọ̀ òdì sí ìjòyè* nínú àwọn èèyàn rẹ.+ Oníwàásù 10:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kódà nínú èrò rẹ,* má ṣe bú* ọba,+ má sì bú olówó nínú yàrá rẹ; torí pé ẹyẹ kan* lè gbé ọ̀rọ̀* náà tàbí kí ohun tó ní ìyẹ́ tún ọ̀rọ̀ rẹ sọ.
20 Kódà nínú èrò rẹ,* má ṣe bú* ọba,+ má sì bú olówó nínú yàrá rẹ; torí pé ẹyẹ kan* lè gbé ọ̀rọ̀* náà tàbí kí ohun tó ní ìyẹ́ tún ọ̀rọ̀ rẹ sọ.