-
2 Sámúẹ́lì 17:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ibikíbi tí a bá ti rí i la ti máa bá a jà, a ó sì ya bò ó bí ìrì ṣe máa ń sẹ̀ sórí ilẹ̀; ẹyọ kan lára wọn ò ní ṣẹ́ kù, àtòun àti àwọn ọkùnrin tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀.
-