25 Torí pé lónìí, ó ti lọ fi akọ màlúù àti ẹran àbọ́sanra pẹ̀lú àgùntàn tó pọ̀ gan-an rúbọ,+ ó pe gbogbo ọmọ ọba àti àwọn olórí ọmọ ogun pẹ̀lú àlùfáà Ábíátárì.+ Wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀, tí wọ́n ń jẹ, tí wọ́n sì ń mu, wọ́n ń sọ pé, ‘Kí ẹ̀mí Ọba Ádóníjà gùn o!’