2 Sámúẹ́lì 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nírọ̀lẹ́ ọjọ́* kan, Dáfídì dìde lórí ibùsùn rẹ̀, ó sì ń rìn lórí òrùlé ilé* ọba. Láti orí òrùlé náà, ó rí obìnrin kan tó ń wẹ̀, obìnrin náà sì rẹwà gan-an.
2 Nírọ̀lẹ́ ọjọ́* kan, Dáfídì dìde lórí ibùsùn rẹ̀, ó sì ń rìn lórí òrùlé ilé* ọba. Láti orí òrùlé náà, ó rí obìnrin kan tó ń wẹ̀, obìnrin náà sì rẹwà gan-an.