-
2 Sámúẹ́lì 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Sádókù+ ọmọ Áhítúbù àti Áhímélékì ọmọ Ábíátárì ni àlùfáà, Seráyà sì ni akọ̀wé.
-
-
2 Sámúẹ́lì 15:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Ṣebí àlùfáà Sádókù àti Ábíátárì wà níbẹ̀ pẹ̀lú rẹ? Gbogbo ohun tí o bá gbọ́ ní ilé ọba+ ni kí o sọ fún àlùfáà Sádókù àti Ábíátárì.
-