1 Àwọn Ọba 1:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Jónátánì+ ọmọ àlùfáà Ábíátárì dé. Ìgbà náà ni Ádóníjà sọ pé: “Wọlé wá, torí èèyàn dáadáa* ni ọ́, ó dájú pé ìròyìn ayọ̀ lo mú wá.”
42 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Jónátánì+ ọmọ àlùfáà Ábíátárì dé. Ìgbà náà ni Ádóníjà sọ pé: “Wọlé wá, torí èèyàn dáadáa* ni ọ́, ó dájú pé ìròyìn ayọ̀ lo mú wá.”