-
Jóṣúà 12:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Síhónì+ ọba àwọn Ámórì, tó ń gbé ní Hẹ́ṣíbónì, tó sì ń jọba láti Áróérì,+ tó wà létí Àfonífojì Áánónì+ àti láti àárín àfonífojì náà àti ìdajì Gílíádì títí dé Àfonífojì Jábókù, ààlà àwọn ọmọ Ámónì. 3 Ó tún jọba lé Árábà títí dé Òkun Kínérétì*+ lápá ìlà oòrùn títí dé Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ní ìlà oòrùn sí Bẹti-jẹ́ṣímótì àti sí apá gúúsù lábẹ́ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà.+
-