-
2 Sámúẹ́lì 18:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọba sọ fún wọn pé: “Ohun tí ẹ bá rí pé ó dára jù ni màá ṣe.” Torí náà, ọba dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè ìlú, gbogbo àwọn èèyàn náà sì jáde lọ ní ọgọ́rọ̀ọ̀rún àti ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún.
-