2 Sámúẹ́lì 22:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Jèhófà wà láàyè! Ìyìn ni fún Àpáta mi!+ Kí a gbé Ọlọ́run tó jẹ́ àpáta ìgbàlà mi ga.+ Sáàmù 144:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 144 Ìyìn ni fún Jèhófà, Àpáta mi,+Ẹni tó ń kọ́ ọwọ́ mi ní ìjàÀti ìka mi ní ogun.+