-
2 Sámúẹ́lì 18:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nígbà náà, Jóábù sọ fún ọmọ Kúṣì+ kan pé: “Lọ sọ ohun tí o rí fún ọba.” Ni ọmọ Kúṣì náà bá tẹrí ba fún Jóábù, ó sì sáré lọ.
-