-
2 Sámúẹ́lì 18:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Wọ́n gbé Ábúsálómù, wọ́n sọ ọ́ sínú kòtò ńlá kan nínú igbó, wọ́n sì kó òkúta lé e lórí pelemọ.+ Gbogbo Ísírẹ́lì sì sá lọ sí ilé wọn.
-