2 Sámúẹ́lì 23:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n Jóábù ọmọ Seruáyà+ ni olórí àwọn mẹ́ta míì; ó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), òun náà sì lórúkọ bí àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.+
18 Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n Jóábù ọmọ Seruáyà+ ni olórí àwọn mẹ́ta míì; ó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), òun náà sì lórúkọ bí àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.+