2 Sámúẹ́lì 16:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba wá sọ fún Síbà pé: “Wò ó! Kí gbogbo ohun tó jẹ́ ti Méfíbóṣétì di tìrẹ.”+ Síbà sọ pé: “Mo tẹrí ba níwájú rẹ. Jẹ́ kí n rí ojú rere rẹ, olúwa mi ọba.”+
4 Ọba wá sọ fún Síbà pé: “Wò ó! Kí gbogbo ohun tó jẹ́ ti Méfíbóṣétì di tìrẹ.”+ Síbà sọ pé: “Mo tẹrí ba níwájú rẹ. Jẹ́ kí n rí ojú rere rẹ, olúwa mi ọba.”+