Nọ́ńbà 35:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹ ò gbọ́dọ̀ gba ìràpadà fún ẹ̀mí* apààyàn tí ikú tọ́ sí, ṣe ni kí ẹ pa á.+