2 Sámúẹ́lì 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó fi wọ́n lé àwọn ará Gíbíónì lọ́wọ́, wọ́n sì gbé òkú wọn kọ́ sórí òkè níwájú Jèhófà.+ Àwọn méjèèje ló kú pa pọ̀, ọjọ́ àkọ́kọ́ ìkórè ni wọ́n pa wọ́n, ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè ọkà bálì.
9 Ó fi wọ́n lé àwọn ará Gíbíónì lọ́wọ́, wọ́n sì gbé òkú wọn kọ́ sórí òkè níwájú Jèhófà.+ Àwọn méjèèje ló kú pa pọ̀, ọjọ́ àkọ́kọ́ ìkórè ni wọ́n pa wọ́n, ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè ọkà bálì.