1 Sámúẹ́lì 17:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ni akọgun kan bá jáde láti ibùdó àwọn Filísínì, Gòláyátì ni orúkọ rẹ̀,+ ará Gátì ni,+ gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà àti ìbú àtẹ́lẹwọ́ kan.* 1 Sámúẹ́lì 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ,*+ ìwọ̀n irin tí wọ́n fi ṣe aṣóró ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ṣékélì;* ẹni tó ń bá a gbé apata sì ń lọ níwájú rẹ̀.
4 Ni akọgun kan bá jáde láti ibùdó àwọn Filísínì, Gòláyátì ni orúkọ rẹ̀,+ ará Gátì ni,+ gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà àti ìbú àtẹ́lẹwọ́ kan.*
7 Igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ,*+ ìwọ̀n irin tí wọ́n fi ṣe aṣóró ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ṣékélì;* ẹni tó ń bá a gbé apata sì ń lọ níwájú rẹ̀.