Ẹ́kísódù 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní àárọ̀ ọjọ́ kẹta, ààrá sán, mànàmáná kọ. Àwọsánmà ṣú+ bo orí òkè, ìró ìwo sì dún sókè gan-an, ẹ̀rù wá ń ba gbogbo àwọn tó wà nínú àgọ́.+ 1 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+
16 Ní àárọ̀ ọjọ́ kẹta, ààrá sán, mànàmáná kọ. Àwọsánmà ṣú+ bo orí òkè, ìró ìwo sì dún sókè gan-an, ẹ̀rù wá ń ba gbogbo àwọn tó wà nínú àgọ́.+
10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+