-
Sáàmù 7:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó ń ṣètò àwọn ohun ìjà rẹ̀ tó ń ṣekú pani sílẹ̀;
Ó ń mú kí àwọn ọfà rẹ̀ tó ń jó fòfò wà ní sẹpẹ́.+
-
-
Sáàmù 77:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọsánmà da omi sílẹ̀.
Ojú ọ̀run tó ṣú dẹ̀dẹ̀ sán ààrá,
Àwọn ọfà rẹ sì ń fò síbí sọ́hùn-ún.+
-