-
Diutarónómì 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí o má bàa gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run rẹ, rí i pé o pa àwọn òfin rẹ̀, ìdájọ́ rẹ̀ àti àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí.
-