Sáàmù 37:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo,Kò sì ní kọ àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀ sílẹ̀.+ ע [Áyìn] Ìgbà gbogbo ni yóò máa ṣọ́ wọn;+Àmọ́ a ó pa àtọmọdọ́mọ àwọn ẹni burúkú rẹ́.+ Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+
28 Nítorí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo,Kò sì ní kọ àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀ sílẹ̀.+ ע [Áyìn] Ìgbà gbogbo ni yóò máa ṣọ́ wọn;+Àmọ́ a ó pa àtọmọdọ́mọ àwọn ẹni burúkú rẹ́.+
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+