Sáàmù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọ̀rọ̀ Jèhófà mọ́;+Wọ́n dà bíi fàdákà tí a yọ́ mọ́ nínú iná ìléru tí wọ́n fi amọ̀ ṣe,* èyí tí a yọ́ mọ́ ní ìgbà méje. Òwe 30:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mọ́.+ Ó* jẹ́ apata fún àwọn tó ń wá ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀.+
6 Àwọn ọ̀rọ̀ Jèhófà mọ́;+Wọ́n dà bíi fàdákà tí a yọ́ mọ́ nínú iná ìléru tí wọ́n fi amọ̀ ṣe,* èyí tí a yọ́ mọ́ ní ìgbà méje.