-
1 Sámúẹ́lì 23:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ bá lọ sí Kéílà, ó sì bá àwọn Filísínì jà; ó kó àwọn ẹran ọ̀sìn wọn lọ, ó pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ, Dáfídì sì gba àwọn tó ń gbé ní Kéílà+ sílẹ̀.
-