Sáàmù 130:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jáà,* tó bá jẹ́ pé àṣìṣe lò ń wò,*Jèhófà, ta ló lè dúró?+ Hósíà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí,Ẹ sọ fún un pé, ‘Jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ kí o sì gba ohun rere tí a mú wá,A ó sì fi ètè wa rú ẹbọ ìyìn sí ọ+ bí ẹni fi akọ ọmọ màlúù rúbọ.* 1 Jòhánù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+
2 Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí,Ẹ sọ fún un pé, ‘Jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ kí o sì gba ohun rere tí a mú wá,A ó sì fi ètè wa rú ẹbọ ìyìn sí ọ+ bí ẹni fi akọ ọmọ màlúù rúbọ.*
9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+