1 Sámúẹ́lì 14:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Kíṣì+ ni bàbá Sọ́ọ̀lù, Nérì+ bàbá Ábínérì sì ni ọmọ Ábíélì.