2 Sámúẹ́lì 24:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí náà, ọba sọ fún Jóábù+ olórí àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lọ yí ká gbogbo àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì, láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà,+ kí ẹ sì forúkọ àwọn èèyàn náà sílẹ̀, kí n lè mọ iye wọn.”
2 Nítorí náà, ọba sọ fún Jóábù+ olórí àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lọ yí ká gbogbo àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì, láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà,+ kí ẹ sì forúkọ àwọn èèyàn náà sílẹ̀, kí n lè mọ iye wọn.”