ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 21:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Nígbà tí Dáfídì gbójú sókè, ó rí áńgẹ́lì Jèhófà tó dúró láàárín ayé àti ọ̀run pẹ̀lú idà tó fà yọ+ ní ọwọ́ rẹ̀, tí ó sì nà án sí Jerúsálẹ́mù. Ní kíá, Dáfídì àti àwọn àgbààgbà tí wọ́n fi aṣọ ọ̀fọ̀*+ bora wólẹ̀, wọ́n sì dojú bolẹ̀.+ 17 Dáfídì sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé: “Ṣebí èmi ni mo ní kí wọ́n lọ ka àwọn èèyàn náà! Èmi ni mo ṣẹ̀, èmi ni mo sì ṣe ohun tí kò dáa;+ àmọ́ kí ni àwọn àgùntàn yìí ṣe? Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi, jọ̀ọ́, èmi àti ilé bàbá mi ni kí o gbé ọwọ́ rẹ sókè sí; má ṣe mú àjàkálẹ̀ àrùn yìí wá sórí àwọn èèyàn rẹ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́