-
2 Sámúẹ́lì 3:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Nígbà tí Ábínérì àti ogún (20) ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀ dé ọ̀dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì, Dáfídì se àsè fún Ábínérì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀.
-