Àwọn Onídàájọ́ 20:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí náà, gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì lọ sí Bẹ́tẹ́lì. Wọ́n sunkún, wọ́n sì jókòó síbẹ̀ níwájú Jèhófà,+ wọ́n gbààwẹ̀+ lọ́jọ́ yẹn títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ níwájú Jèhófà.
26 Torí náà, gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì lọ sí Bẹ́tẹ́lì. Wọ́n sunkún, wọ́n sì jókòó síbẹ̀ níwájú Jèhófà,+ wọ́n gbààwẹ̀+ lọ́jọ́ yẹn títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ níwájú Jèhófà.