1 Àwọn Ọba 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ṣíméì ọmọ Gérà ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Báhúrímù náà wà nítòsí rẹ. Òun ló ń ṣẹ́ èpè burúkú+ lé mi lórí lọ́jọ́ tí mò ń lọ sí Máhánáímù;+ àmọ́ nígbà tó wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Jèhófà búra fún un pé: ‘Mi ò ní fi idà pa ọ́.’+
8 “Ṣíméì ọmọ Gérà ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Báhúrímù náà wà nítòsí rẹ. Òun ló ń ṣẹ́ èpè burúkú+ lé mi lórí lọ́jọ́ tí mò ń lọ sí Máhánáímù;+ àmọ́ nígbà tó wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Jèhófà búra fún un pé: ‘Mi ò ní fi idà pa ọ́.’+