-
1 Àwọn Ọba 2:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Ṣíméì dá ọba lóhùn pé: “Ohun tí o sọ dára. Ìránṣẹ́ rẹ yóò ṣe ohun tí olúwa mi ọba sọ.” Torí náà, ọ̀pọ̀ ọjọ́ ni Ṣíméì fi gbé ní Jerúsálẹ́mù.
-