-
1 Sámúẹ́lì 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Lẹ́yìn náà, lọ sí Gílígálì+ kí n tó dé, màá sì wá bá ọ níbẹ̀ láti rú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀. Ọjọ́ méje ni kí o fi dúró títí màá fi wá bá ọ. Ìgbà yẹn ni màá jẹ́ kí o mọ ohun ti wàá ṣe.”
-