Oníwàásù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Wò ó! Mo ti ní ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an ju ẹnikẹ́ni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù,+ ọkàn mi sì ti kó ọgbọ́n àti ìmọ̀+ tó pọ̀ gan-an jọ.” 1 Jòhánù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tó dá wa lójú nípa rẹ̀ ni pé,*+ tí a bá béèrè ohunkóhun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu, ó ń gbọ́ wa.+
16 Nígbà náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Wò ó! Mo ti ní ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an ju ẹnikẹ́ni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù,+ ọkàn mi sì ti kó ọgbọ́n àti ìmọ̀+ tó pọ̀ gan-an jọ.”