1 Àwọn Ọba 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí náà, ọrọ̀+ àti ọgbọ́n+ Ọba Sólómọ́nì pọ̀ ju ti gbogbo àwọn ọba yòókù láyé.