-
1 Kíróníkà 27:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn aṣáájú àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì nìyí: Nínú àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, Élíésérì ọmọ Síkírì ni aṣáájú; nínú àwọn ọmọ Síméónì, Ṣẹfatáyà ọmọ Máákà; 17 nínú ẹ̀yà Léfì, Haṣabáyà ọmọ Kémúélì; nínú àwọn ọmọ Áárónì, Sádókù;
-